Yoruba Hymns -Oluwa ran mi ni 'ṣẹ Aleluya
Click : https://youtu.be/tE2-o1gO8R8Lyrics
1. Oluwa ran mi ni ‘se, Aleluya!Iwo ni uno je ise na fun;
A ko s‘inu Oro Re, Aleluya!
P‘eni t‘o ba wo Jesu y‘o ye.
Wo, k‘o ye, Arakunrin,
Wo Jesu ki o si ye,
A ko s‘inu Oro Re, Aleluya!
P‘eni t‘o ba wo Jesu y‘o ye.
2. A ran mi n‘ise ayo, Aleluya!
Uno j‘isena fun o ore mi;
Ise lat‘ oke wa ni; Aleluya!
Jesu SO, mo mo pe oto ni.
3. A n‘owo iye si O, Aleluya!
A o fi ‘ye ailopin fun O;
T‘o ba wo Jesu nikan, Aleluya!
Wo o, On nikan l‘o le gbala. .
No comments:
Post a Comment